Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 3:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kò ní rí ìjì tabi òjò, sibẹsibẹ àwọn odò gbígbẹ náà yóo kún fún omi, ti yóo fi jẹ́ pé ẹ̀yin ati àwọn mààlúù yín ati àwọn ẹran ọ̀sìn yín yóo rí ọpọlọpọ omi mu.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 3

Wo Àwọn Ọba Keji 3:17 ni o tọ