Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 3:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Eliṣa bá dáhùn pé, “Bí OLUWA àwọn ọmọ ogun, ẹni tí mò ń sìn ṣe wà láàyè, n kì bá tí dá ọ lóhùn bí kò bá sí ti Jehoṣafati, ọba Juda, tí ó bá ọ wá.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 3

Wo Àwọn Ọba Keji 3:14 ni o tọ