Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 3:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún kejidinlogun tí Jehoṣafati jọba ní Juda, Joramu, ọmọ Ahabu, jọba lórí Israẹli ní Samaria. Ó sì wà lórí oyè fún ọdún mejila.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 3

Wo Àwọn Ọba Keji 3:1 ni o tọ