Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 24:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni ọdún mọkanlelogun ni Sedekaya nígbà tí ó wà lórí oyè, ó sì jọba ní Jerusalẹmu fún ọdún mọkanla. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Hamutali, ọmọ Jeremaya ará Libina.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 24

Wo Àwọn Ọba Keji 24:18 ni o tọ