Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 24:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò náà ni àwọn ọmọ ogun Nebukadinesari, ọba Babiloni, lọ gbógun ti Jerusalẹmu, wọ́n sì dó tì í.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 24

Wo Àwọn Ọba Keji 24:10 ni o tọ