Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 23:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo wọn lọ sí ilé OLUWA pẹlu àwọn alufaa ati àwọn wolii ati gbogbo àwọn eniyan, àtọmọdé àtàgbà wọn. Ọba bá ka ìwé majẹmu tí wọ́n rí ninu ilé OLUWA sí etígbọ̀ọ́ wọn.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 23

Wo Àwọn Ọba Keji 23:2 ni o tọ