Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 23:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní gbogbo àwọn ìlú Israẹli ni Josaya ti wó àwọn ilé oriṣa tí àwọn ọba Israẹli kọ́ tí ó bí OLUWA ninu. Bí ó ti ṣe pẹpẹ ìrúbọ tí ó wà ní Bẹtẹli ni ó ṣe àwọn pẹpẹ ìrúbọ náà.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 23

Wo Àwọn Ọba Keji 23:19 ni o tọ