Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 23:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Josaya Ọba wó ilé oriṣa Tofeti tí ó wà ní àfonífojì Hinomu, kí ẹnikẹ́ni má baà lè fi ọmọkunrin tabi ọmọbinrin rẹ̀ rúbọ sí oriṣa Moleki mọ́.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 23

Wo Àwọn Ọba Keji 23:10 ni o tọ