Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 22:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣafani bá pada lọ jíṣẹ́ fún ọba, ó sọ fún ọba pé, àwọn iranṣẹ rẹ̀ ti kó owó tí ó wà ninu ilé OLUWA fún àwọn tí wọ́n ń ṣe àkóso àtúnṣe ilé OLUWA,

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 22

Wo Àwọn Ọba Keji 22:9 ni o tọ