Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 21:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó gbẹ́ ère Aṣera tí ó gbé sinu ilé OLUWA, ibi tí OLUWA ti sọ fún Dafidi ati Solomoni pé, “Ninu ilé yìí, àní, ní Jerusalẹmu, ni mo yàn láàrin àwọn ìlú àwọn ẹ̀yà mejeejila Israẹli, gẹ́gẹ́ bí ibi tí ẹ óo ti máa sìn mí títí lae.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 21

Wo Àwọn Ọba Keji 21:7 ni o tọ