Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 20:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Aisaya dáhùn pé, “OLUWA yóo fún ọ ní àmì láti fihàn pé òun yóo mú ìlérí òun ṣẹ. Èwo ni o fẹ́, ninu kí òjìji lọ siwaju ní ẹsẹ̀ mẹ́wàá tabi kí ó pada sẹ́yìn ní ẹsẹ̀ mẹ́wàá?”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 20

Wo Àwọn Ọba Keji 20:9 ni o tọ