Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 2:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Elija bọ́ aṣọ àwọ̀lékè rẹ̀, ó fi lu odò náà, odò sì pín sí meji títí tí Elija ati Eliṣa fi kọjá sí òdìkejì odò lórí ìyàngbẹ ilẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 2

Wo Àwọn Ọba Keji 2:8 ni o tọ