Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 19:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó gbadura pé, “OLUWA Ọlọrun Israẹli, tí ń gbé láàrin àwọn Kerubu, ìwọ nìkan ni Ọlọrun tí ń jọba lórí gbogbo ilẹ̀ ayé, ìwọ ni o dá ayé ati ọ̀run.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 19

Wo Àwọn Ọba Keji 19:15 ni o tọ