Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 18:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Hesekaya ní igbagbọ ninu OLUWA Ọlọrun Israẹli. Juda kò sì ní ọba mìíràn tí ó dà bíi rẹ̀, yálà ṣáájú rẹ̀ ni, tabi lẹ́yìn rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 18

Wo Àwọn Ọba Keji 18:5 ni o tọ