Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 18:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní kí ẹ má ṣe jẹ́ kí ó mú ki ẹ gbẹ́kẹ̀lé OLUWA kí ó máa sọ pé OLUWA yóo gbà yín sílẹ̀, ati pé kò ní jẹ́ kí ogun Asiria kó ìlú yín.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 18

Wo Àwọn Ọba Keji 18:30 ni o tọ