Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 18:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni Eliakimu, ọmọ Hilikaya ati Ṣebina ati Joa sọ fún Rabuṣake pé, “Jọ̀wọ́, bá àwa iranṣẹ rẹ sọ̀rọ̀ ní èdè Aramaiki nítorí pé a gbọ́. Má sọ èdè Heberu mọ́, nítorí pé àwọn tí wọ́n wà lórí odi ń gbọ́ ohun tí ò ń sọ.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 18

Wo Àwọn Ọba Keji 18:26 ni o tọ