Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 18:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kò lè ṣẹgun ẹni tí ó kéré jùlọ ninu àwọn ọ̀gágun ọba Asiria, sibẹ o rò pé àwọn kẹ̀kẹ́ ogun ati àwọn ẹlẹ́ṣin ọba Ijipti yóo ràn ọ́ lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 18

Wo Àwọn Ọba Keji 18:24 ni o tọ