Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 18:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣé Ijipti ni ó gbójú lé pé yóo ran òun lọ́wọ́? Ó ní ọ̀rọ̀ rẹ̀ dàbí ẹni tí ó ń fi igi tí kò ní agbára ṣe ọ̀pá ìtilẹ̀. Tí igi náà bá dá, yóo gún un lọ́wọ́. Bẹ́ẹ̀ ni ọba Ijipti rí sí gbogbo àwọn tí wọ́n bá gbẹ́kẹ̀ wọn lé e.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 18

Wo Àwọn Ọba Keji 18:21 ni o tọ