Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 17:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ní ọdún kan, Hoṣea ranṣẹ sí So, ọba Ijipti pé, kí ó ran òun lọ́wọ́, kò sì san ìṣákọ́lẹ̀ fún ọba Asiria mọ́. Nígbà tí Ṣalimaneseri gbọ́, ó pàṣẹ pé kí wọ́n ju Hoṣea sinu ọgbà ẹ̀wọ̀n.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 17

Wo Àwọn Ọba Keji 17:4 ni o tọ