Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 17:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí OLUWA ti fi ìyapa sí ààrin Israẹli ati ìdílé Dafidi, Israẹli fi Jeroboamu ọmọ Nebati jọba. Jeroboamu mú kí wọ́n kọ OLUWA sílẹ̀, ó sì mú kí wọ́n dẹ́ṣẹ̀ ńlá.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 17

Wo Àwọn Ọba Keji 17:21 ni o tọ