Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 17:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Sibẹ, OLUWA ń rán àwọn iranṣẹ rẹ̀ ati àwọn wolii rẹ̀ kí wọ́n máa kìlọ̀ fún Israẹli ati Juda pé, “Ẹ kọ ọ̀nà burúkú yín sílẹ̀ kí ẹ sì pa òfin ati ìlànà mi, tí mo fún àwọn baba ńlá yín mọ́; àní àwọn tí mo fun yín nípasẹ̀ àwọn wolii, iranṣẹ mi.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 17

Wo Àwọn Ọba Keji 17:13 ni o tọ