Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 17:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ní ọdún kejila tí Ahasi jọba ní Juda, ni Hoṣea ọmọ Ela jọba lórí Israẹli, ní Samaria, ó sì jọba fún ọdún mẹsan-an.

2. Ó ṣe nǹkan tí ó burú lójú OLUWA, ṣugbọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ kò tó ti àwọn ọba tí wọ́n jẹ ṣáájú rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 17