Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 16:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Resini, ọba Siria, ati Peka, ọba Israẹli, gbógun ti Jerusalẹmu, wọ́n sì dó ti Ahasi, ṣugbọn wọn kò lè ṣẹgun rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 16

Wo Àwọn Ọba Keji 16:5 ni o tọ