Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 16:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni ogún ọdún ni Ahasi nígbà tí ó jọba, ó sì wà lórí oyè fún ọdún mẹrindinlogun. Kò tẹ̀lé àpẹẹrẹ rere Dafidi baba ńlá rẹ̀, ṣugbọn ó ṣẹ̀ sí OLUWA Ọlọrun rẹ̀,

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 16

Wo Àwọn Ọba Keji 16:2 ni o tọ