Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 16:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Pẹpẹ idẹ tí a ti yà sọ́tọ̀ fún OLUWA wà ní ààrin pẹpẹ tirẹ̀ ati ilé OLUWA. Nítorí náà, Ahasi gbé pẹpẹ idẹ náà sí apá òkè pẹpẹ tirẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 16

Wo Àwọn Ọba Keji 16:14 ni o tọ