Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 16:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Ahasi lọ pàdé Tigilati Pileseri ọba, ní Damasku, ó rí pẹpẹ ìrúbọ kan níbẹ̀, ó sì ranṣẹ sí Uraya alufaa pé kí ó mọ irú rẹ̀ gan-an láìsí ìyàtọ̀ kankan.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 16

Wo Àwọn Ọba Keji 16:10 ni o tọ