Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 15:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ogún ọdún tí Jotamu, ọmọ Usaya jọba Juda, ni Hoṣea, ọmọ Ela, dìtẹ̀ mọ́ Peka ọba, ó pa á, ó sì jọba dípò rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 15

Wo Àwọn Ọba Keji 15:30 ni o tọ