Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 15:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún kejilelaadọta tí Asaraya jọba ní Juda, ni Peka, ọmọ Remalaya, jọba lórí Israẹli ní Samaria, ó sì wà lórí oyè fún ogún ọdún.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 15

Wo Àwọn Ọba Keji 15:27 ni o tọ