Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 15:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni ọdún mẹrindinlogun ni nígbà tí ó jọba, ó sì wà lórí oyè ní Jerusalẹmu fún ọdún mejilelaadọta. Jekolaya ará Jerusalẹmu ni ìyá rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 15

Wo Àwọn Ọba Keji 15:2 ni o tọ