Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 13:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jehoahasi gbadura sí OLUWA, tí OLUWA sì rí ìyà tí Hasaeli fi ń jẹ àwọn eniyan Israẹli, ó gbọ́ adura rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 13

Wo Àwọn Ọba Keji 13:4 ni o tọ