Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 13:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún kẹtalelogun tí Joaṣi, ọmọ Ahasaya, jọba ní Juda ni Jehoahasi, ọmọ Jehu, jọba lórí Israẹli ní Samaria, ó jọba fún ọdún mẹtadinlogun.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 13

Wo Àwọn Ọba Keji 13:1 ni o tọ