Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 12:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ó pe Jehoiada ati àwọn alufaa yòókù, ó bèèrè pé, “Kí ló dé tí ẹ kò fi tún ilé OLUWA ṣe? Láti ìsinsìnyìí lọ, ẹ gbọdọ̀ máa kó owó tí ẹ bá gbà sílẹ̀ fún àtúnṣe ilé OLUWA.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 12

Wo Àwọn Ọba Keji 12:7 ni o tọ