Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 12:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Josakari, ọmọ Ṣimeati ati Jehosabadi, ọmọ Ṣomeri, àwọn olórí ogun, ni wọ́n pa á. Wọ́n sì sin ín sí ibojì àwọn baba rẹ̀ ní ìlú Dafidi. Amasaya ọmọ rẹ̀ sì jọba lẹ́yìn rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 12

Wo Àwọn Ọba Keji 12:21 ni o tọ