Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 11:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, àwọn eniyan lọ sí ilé oriṣa Baali, wọ́n wó o, wọ́n sì wó àwọn pẹpẹ rẹ̀ ati àwọn ère rẹ̀ lulẹ̀. Wọ́n pa Matani, alufaa Baali, níwájú àwọn pẹpẹ náà.Jehoiada sì fi àwọn olùṣọ́ tí wọ́n wà lẹ́nu iṣẹ́ sí ìtọ́jú ilé OLUWA.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 11

Wo Àwọn Ọba Keji 11:18 ni o tọ