Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 10:26-28 BIBELI MIMỌ (BM)

26. wọ́n kó gbogbo àwọn ère tí wọ́n wà níbẹ̀ jáde, wọ́n sì sun wọ́n níná.

27. Wọ́n wó àwọn ère ati ilé ìsìn Baali lulẹ̀, wọ́n sì sọ ibẹ̀ di ilé ìgbẹ́ títí di òní yìí.

28. Bẹ́ẹ̀ ni Jehu ṣe pa ìsìn Baali run ní Israẹli.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 10