Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 10:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Jehu pàṣẹ pé kí àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ mú wọn láàyè. Wọ́n mú wọn láàyè, wọ́n sì pa wọ́n ní ibi kòtò tí ó wà ní Bẹtekedi. Gbogbo wọn jẹ́ mejilelogoji, kò sì dá ọ̀kankan ninu wọn sí.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 10

Wo Àwọn Ọba Keji 10:14 ni o tọ