Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 1:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ahasaya sì kú gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ OLUWA tí Elija sọ. Ṣugbọn nítorí pé kò ní ọmọkunrin kankan Joramu, arakunrin rẹ̀ jọba lẹ́yìn rẹ̀, ní ọdún keji tí Jehoramu ọmọ Jehoṣafati jọba ní Juda.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 1

Wo Àwọn Ọba Keji 1:17 ni o tọ