Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 1:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni angẹli OLUWA sọ fún Elija pé kí ó bá wọn lọ, kí ó má sì bẹ̀rù. Elija bá bá a lọ sọ́dọ̀ ọba.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 1

Wo Àwọn Ọba Keji 1:15 ni o tọ