Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 9:56 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni Ọlọrun ṣe gbẹ̀san lára Abimeleki fún ẹ̀ṣẹ̀ tí ó ṣẹ baba rẹ̀, nítorí pé, ó pa aadọrin àwọn arakunrin rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 9

Wo Àwọn Adájọ́ 9:56 ni o tọ