Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 9:44 BIBELI MIMỌ (BM)

Abimeleki ati àwọn ẹgbẹ́ ọmọ ogun tí wọ́n wà lọ́dọ̀ rẹ̀ sáré, wọ́n lọ gba ẹnu ọ̀nà bodè ìlú. Àwọn ẹgbẹ́ ọmọ ogun meji yòókù sáré sí gbogbo àwọn tí wọ́n wà ninu pápá, wọ́n pa wọ́n.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 9

Wo Àwọn Adájọ́ 9:44 ni o tọ