Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 9:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Gaali tún dáhùn, ó ní, “Tún wò ó, àwọn eniyan kan ń bọ̀ láti agbede meji ilẹ̀ náà, àwọn kan sì ń bọ̀ láti apá ibi igi Oaku àwọn tíí máa ń wo iṣẹ́.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 9

Wo Àwọn Adájọ́ 9:37 ni o tọ