Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 9:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ilẹ̀ bá ti mọ́, tí oòrùn sì bẹ̀rẹ̀ sí yọ, gbéra, kí o sì gbógun ti ìlú náà. Nígbà tí Gaali ati àwọn ọkunrin tí wọ́n wà pẹlu rẹ̀ bá sì jáde sí ọ, mú wọn dáradára, kí o sì ṣe ẹ̀tọ́ fún wọn.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 9

Wo Àwọn Adájọ́ 9:33 ni o tọ