Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 9:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará ìlú Ṣekemu lọ sinu oko wọn, wọ́n ká èso àjàrà, wọ́n fi pọn ọtí fún wọn. Wọ́n jọ ń ṣe àríyá, wọ́n jọ lọ sí ilé oriṣa wọn, wọ́n ń jẹ, wọ́n ń mu, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí fi Abimeleki ṣe ẹlẹ́yà.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 9

Wo Àwọn Adájọ́ 9:27 ni o tọ