Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 9:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun rán ẹ̀mí burúkú sí ààrin Abimeleki ati àwọn ara ìlú Ṣekemu. Àwọn ará ìlú Ṣekemu sì dìtẹ̀ mọ́ Abimeleki.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 9

Wo Àwọn Adájọ́ 9:23 ni o tọ