Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 9:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí bẹ́ẹ̀ kọ́, iná yóo jáde láti ara Abimeleki, yóo sì run gbogbo àwọn ará ìlú Ṣekemu ati Bẹtimilo. Bẹ́ẹ̀ ni iná yóo jáde láti ara àwọn ará ìlú Ṣekemu ati ti Bẹtimilo, yóo sì jó Abimeleki run.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 9

Wo Àwọn Adájọ́ 9:20 ni o tọ