Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 9:16 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ǹjẹ́ òtítọ́ inú ati ọ̀nà ẹ̀tọ́ ni ẹ fi fi Abimeleki jọba? Ṣé ohun tí ẹ ṣe sí ìdílé Gideoni tọ́? Gbogbo sísìn tí ó sìn yín, ǹjẹ́ irú ohun tí ó yẹ kí ẹ fi san án fún un nìyí?

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 9

Wo Àwọn Adájọ́ 9:16 ni o tọ