Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 8:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ìwọ̀n yẹtí wúrà tí ó gbà jẹ́ ẹẹdẹgbẹsan (1,700) ṣekeli, láìka ohun ọ̀ṣọ́ ati aṣọ olówó iyebíye tí àwọn ọba Midiani wọ̀, ati àwọn nǹkan ọ̀ṣọ́ tí ó wà lọ́rùn àwọn ràkúnmí wọn.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 8

Wo Àwọn Adájọ́ 8:26 ni o tọ