Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 8:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ó bi Seba ati Salimuna pé, “Níbo ni àwọn ọkunrin tí ẹ pa ní Tabori wà?” Wọ́n dá a lóhùn pé, “Bí o ti rí gan-an ni ẹnìkọ̀ọ̀kan wọn náà rí, gbogbo wọn dàbí ọmọ ọba.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 8

Wo Àwọn Adájọ́ 8:18 ni o tọ