Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 8:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Seba ati Salimuna wà ní ìlú Karikori pẹlu àwọn ọmọ ogun wọn yòókù, gbogbo àwọn ọmọ ogun ìlà oòrùn tí wọ́n ṣẹ́kù kò ju nǹkan bí ẹẹdẹgbaajọ (15,000) lọ, nítorí pé àwọn tí wọ́n ti kú ninu àwọn ọmọ ogun wọn tí wọ́n ń lo idà tó ọ̀kẹ́ mẹfa (120,000).

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 8

Wo Àwọn Adájọ́ 8:10 ni o tọ