Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 7:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Gideoni bá gba oúnjẹ àwọn eniyan náà ati fèrè ogun wọn lọ́wọ́ wọn, ó sì sọ fún wọn pé kí wọ́n pada sí ilé, ṣugbọn ó dá àwọn ọọdunrun (300) náà dúró. Àgọ́ àwọn ọmọ ogun Midiani wà ní àfonífojì lápá ìsàlẹ̀ ibi tí wọ́n wà.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 7

Wo Àwọn Adájọ́ 7:8 ni o tọ